Featured post

TAOJUSI NU OMI FUN WAKATI 6.......MOFEKI EJEKI AMOWIPE NKAN TOMAN TUYAN SILE NINU OGUN NIGBAMIRAN KEKERE BAYII NII....IDINIYEN TAOFI GBODO ...

Thursday, 5 January 2017

Close
Moki gbogbo egbe patapata lapapo pe aku ojometa ati igba die, asi imura odun, odun ayo ni ao se o, amin, owunmi lati fi asiri yi sita, ki gbogbo eniyan je anfani e, hatimi ti enwo yi ise 201 lonse o, ti awon Alfa alasiri bati ri, won ti damo pe hatimi kahaf ni o, olagbara pupo osi je bi idan ni o, ti abafelofun owo, ao laa hatimi yi 313,si oju opon ola, ao fo, ao wa han suratu kahaf 313 be, ao fo, ao wa oba ikan, ao gbemi ni dede ago mejila oru, ao ma mu omi hantu yan le die, ti yoo fi tan, ao ma sa suratu kahaf 3 ni agomejila oru fun 14days ao wa pa agbo nla toba woju dada,) fun itusile ninu ide, ao laa hatimi yi sinu aso funfun, eni na majokole, ti obaje alaisan ti kole dide rara eni ki iya e tabi alasumon e kan jokole, ao wa ka suratu kahaf 110 fun, koda ki won ti pin Eran e yodide,kete ti abati pari adua na agbodo pa eran o, fun ti eni ti won yokuro ni ipo yala ipo governor or president, or king tabi ise bo lowo e, yo joko sori aso yi, yo wo ewu odi, sokoto odi, fila odi, e wa sa kahaf 110,fun,yobosi,ori ipo na pada,otun sisefun eniti won fepa , koda kojepe won ti fi eyin e ti agba, elomiran ni won ma pa, )fun elemi kukuru) yo joko sori asoyi aowa okan kannakanna yo gbemi, yowa jokosori aso yan, aowa ka suratu kahaf fun 110,ti abati ka mewa ao ma ka lakadijakun 111,titi ti kahaf yan mafipe 110,ao wa pa eran nla kan, yo dagba debipe oun funra e ni o fi enu ara e bere iku,) fun ti isora) ao la hatimi yi 7sinu takada fun fun aowa lo epo oro aije oun ni gari e, ao di ni tira ao ranmo fila ao ma de, (fun eniti won ti yi kadara e pada ti koni owo rara, ao han kahaf 110,pelu hatimi yi 110,mim togbeyin ninu kahaf ao fun loju, ao wa ko aniyan pe ki olorun yi kadara yan pada si ti olowo, (fun eniti olowo ti kofe lole mo lailai, bi ati han ni yan aniyan ti akosi nikan loyato, aniyan ti e nipe kowo na maposi komadin rara, ori odo niwon mati mun ni ago kan oru, won o gbodo fi esekanle ti won afi gbemu.
— with Horladimeji Harloma, Adedeji Seun and Alfa Lukman Akeusola Miqdady.
    Desmond Olayode Olashubomi
    Write a comment...

No comments:

Post a Comment