TAOJUSI NU OMI FUN WAKATI 6.......MOFEKI EJEKI AMOWIPE NKAN TOMAN TUYAN
SILE NINU OGUN NIGBAMIRAN KEKERE BAYII NII....IDINIYEN TAOFI GBODO MAA
FOJU DINKAN.......EJEKI ATUN DAN ISEYII NANWO KONANWA LOWO PUPO
RARA........SUGBON AKEREKORO ABIJAWARA NII.........MOFEKI GBOGBO WA BO
NINU IDE NI DIE TOKU TI ODUN 2016 YII MÀAPARI.........
ATUDE, AWEBI, AWEGUN DANU.........
Aowa omunun lapalapa tosesen yo......3
Ata ijosi 9 fun okr, 7 fun obr
Eepo obo die
Aogun meteeta kunnan....…..aopomo ose dudu iwe eekan pere.....…aoti
koko to ito idaji sinu ibikan..….laitiosoro siyan laaro
kutukutu.…....aowa eko elewe kan.........tobadi ale
patapata.........aofi ito (urine) yen fo eko yen
papo..…..............aowagbelosi ile iwe lale patapata.......aofi
para..…..aowawe oseyen........lojo alokoko...…....tobatundi ojo
elekeji....aotun gun oseyen.....ito wa.....pelu eko nan
laotunfipara..aotun sebee.......ojo eleketa aotun gun oseyen
bakanan....aotun fi ito idaji wa fo eko, aowe oseyen.......
aotunsebee...........tabatiwawetan.....awon keinkein yen....aolobomole
sori akitan tiwonman da ilesii.....tabi kasun ninan.........
NB...........akogbodo gun oseyen sile.... ojoojumo laomaagun fun odidi
ojo meta.....hnmmm eniti olohun basowipe ASIKO gbigba adura
retoo....lomaari iseyii see........enitobawarise yoori awon apere iyanu
kookan yala loju orun tabi loju aye.........kojubeelo.......Aoni jinsi
koto aye oooo..........
HAPPY CHRISTMAS AND NEW YEAR IN ADVANCE TO ALL OF US AT
No comments:
Post a Comment